ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 26:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Kí o fi fàdákà ṣe ogójì (40) ìtẹ́lẹ̀ oníhò+ sábẹ́ ogún (20) férémù náà: ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò sábẹ́ férémù kan, kí ìtẹ̀bọ̀ méjì férémù náà lè wọnú rẹ̀, kí ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò sì wà lábẹ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn férémù yòókù, kí ìtẹ̀bọ̀ méjì férémù náà lè wọnú rẹ̀.+

  • Ẹ́kísódù 38:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ọgọ́rùn-ún (100) tálẹ́ńtì ni wọ́n fi rọ àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò ibi mímọ́ àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò ti aṣọ ìdábùú; ọgọ́rùn-ún (100) tálẹ́ńtì ni wọ́n fi ṣe ọgọ́rùn-ún (100) ìtẹ́lẹ̀ oníhò, tálẹ́ńtì kan fún ìtẹ́lẹ̀ oníhò kọ̀ọ̀kan.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́