Ẹ́kísódù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+ Ẹ́kísódù 13:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 kí ẹ ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* sọ́tọ̀ fún Jèhófà, pẹ̀lú gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn yín tó jẹ́ akọ. Jèhófà ló ni àwọn akọ.+ Léfítíkù 27:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Àmọ́, kí ẹnì kankan má ya àkọ́bí ẹran sí mímọ́, torí ti Jèhófà ni àkọ́bí tí ẹran bá bí.+ Ì báà jẹ́ akọ màlúù tàbí àgùntàn, Jèhófà ló ni ín.+
2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+
12 kí ẹ ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* sọ́tọ̀ fún Jèhófà, pẹ̀lú gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn yín tó jẹ́ akọ. Jèhófà ló ni àwọn akọ.+
26 “‘Àmọ́, kí ẹnì kankan má ya àkọ́bí ẹran sí mímọ́, torí ti Jèhófà ni àkọ́bí tí ẹran bá bí.+ Ì báà jẹ́ akọ màlúù tàbí àgùntàn, Jèhófà ló ni ín.+