- 
	                        
            
            Nọ́ńbà 7:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 àwọn ìjòyè Ísírẹ́lì,+ àwọn olórí agbo ilé bàbá wọn mú ọrẹ wá. Àwọn ìjòyè yìí látinú àwọn ẹ̀yà, tí wọ́n darí ìforúkọsílẹ̀ náà 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Diutarónómì 5:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 “Àmọ́ gbàrà tí ẹ gbọ́ ohùn tó ń tinú òkùnkùn náà jáde, nígbà tí iná ń jó ní òkè náà,+ gbogbo olórí ẹ̀yà yín àti àwọn àgbààgbà wá sọ́dọ̀ mi. 
 
-