ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+

  • Ẹ́kísódù 40:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Tí ìkùukùu bá ti kúrò lórí àgọ́ ìjọsìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa tú àgọ́ wọn ká bí wọ́n ṣe ń lọ láti ibì kan sí ibòmíì lẹ́nu gbogbo ìrìn àjò wọn.+

  • Nọ́ńbà 10:33, 34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní òkè Jèhófà,+ wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta, àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà sì ń lọ níwájú wọn ní ọjọ́ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta láti wá ibi ìsinmi fún wọn.+ 34 Ìkùukùu+ Jèhófà sì wà lórí wọn ní ọ̀sán nígbà tí wọ́n gbéra ní ibùdó.

  • Sáàmù 78:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó fi ìkùukùu* ṣamọ̀nà wọn ní ọ̀sán,

      Ó sì fi ìmọ́lẹ̀ iná ṣamọ̀nà wọn ní gbogbo òru.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́