Jẹ́nẹ́sísì 10:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ 16 àti àwọn ará Jébúsì,+ àwọn Ámórì,+ àwọn Gẹ́gáṣì,