Nọ́ńbà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 nínú ẹ̀yà Júdà, Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè; Nọ́ńbà 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èyí ni orúkọ àwọn ọkùnrin tí Mósè rán láti ṣe amí ilẹ̀ náà. Mósè wá sọ Hóṣéà ọmọ Núnì ní Jóṣúà.*+ Nọ́ńbà 14:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+
30 Ìkankan nínú yín kò ní wọ ilẹ̀ tí mo búra* pé ẹ máa gbé,+ àfi Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè àti Jóṣúà ọmọ Núnì.+