-
Léfítíkù 23:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “‘Èyí ni àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà tó jẹ́ ti Jèhófà, àwọn àpéjọ mímọ́ tí ẹ máa kéde ní àwọn àkókò tí mo yàn fún wọn:
-
-
Nọ́ńbà 28:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “‘Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní ni kó jẹ́ ọjọ́ Ìrékọjá+ sí Jèhófà.
-
-
Diutarónómì 16:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “Ọjọ́ méje ni kí o fi ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà,+ nígbà tí o bá kó ọkà rẹ jọ láti ibi ìpakà, tí o sì mú òróró àti wáìnì jáde láti ibi ìfúntí rẹ.
-