Jẹ́nẹ́sísì 17:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá fún ìwọ àti ọmọ* rẹ ní ilẹ̀ tí o gbé nígbà tí o jẹ́ àjèjì,+ ìyẹn gbogbo ilẹ̀ Kénáánì, yóò jẹ́ ohun ìní wọn títí láé, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run+ wọn.” Ẹ́kísódù 29:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Èmi yóò máa gbé láàárín* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.+ Léfítíkù 25:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì+ láti fún yín ní ilẹ̀ Kénáánì, láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run yín.+
8 Màá fún ìwọ àti ọmọ* rẹ ní ilẹ̀ tí o gbé nígbà tí o jẹ́ àjèjì,+ ìyẹn gbogbo ilẹ̀ Kénáánì, yóò jẹ́ ohun ìní wọn títí láé, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run+ wọn.”
38 Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì+ láti fún yín ní ilẹ̀ Kénáánì, láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run yín.+