-
Nọ́ńbà 18:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Wò ó, mo ti fún àwọn ọmọ Léfì ní gbogbo ìdá mẹ́wàá+ ní Ísírẹ́lì, kó jẹ́ ogún wọn torí iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe, iṣẹ́ àgọ́ ìpàdé.
-
-
Diutarónómì 12:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí ẹ rí i pé ẹ ò gbàgbé ọmọ Léfì+ ní gbogbo ọjọ́ tí ẹ bá fi ń gbé lórí ilẹ̀ yín.
-