Ẹ́kísódù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+ Diutarónómì 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ mọ̀ pé ẹ̀yin ni mò ń bá sọ̀rọ̀ lónìí, kì í ṣe àwọn ọmọ yín tí wọn ò tíì mọ ìbáwí Jèhófà Ọlọ́run yín,+ títóbi rẹ̀,+ ọwọ́ agbára rẹ̀+ àti apá tó nà jáde, tí wọn ò sì tíì rí nǹkan wọ̀nyí.
16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+
2 Ẹ mọ̀ pé ẹ̀yin ni mò ń bá sọ̀rọ̀ lónìí, kì í ṣe àwọn ọmọ yín tí wọn ò tíì mọ ìbáwí Jèhófà Ọlọ́run yín,+ títóbi rẹ̀,+ ọwọ́ agbára rẹ̀+ àti apá tó nà jáde, tí wọn ò sì tíì rí nǹkan wọ̀nyí.