ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 “Tí o bá ń pa gbogbo àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí mò ń pa fún ọ lónìí mọ́ délẹ̀délẹ̀, kí o lè máa rí i pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbé ọ ga ju gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù tó wà láyé+ lọ. 2 Gbogbo ìbùkún yìí máa jẹ́ tìrẹ, ó sì máa bá ọ,+ torí pé ò ń fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run rẹ:

  • Sáàmù 19:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+

      Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+

  • Sáàmù 19:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 A ti fi wọ́n kìlọ̀ fún ìránṣẹ́ rẹ;+

      Èrè ńlá wà nínú pípa wọ́n mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́