ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 7:33-35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Kí ẹsẹ̀ ọ̀tún jẹ́ ìpín+ ọmọ Áárónì tó bá mú ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àti ọ̀rá wá. 34 Torí mo mú igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́ náà látinú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì fún àlùfáà Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kó jẹ́ ìlànà tó máa wà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ títí lọ.

      35 “‘Ìpín tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún àwọn àlùfáà nìyí, fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ní ọjọ́ tó mú wọn wá síwájú Jèhófà láti ṣe àlùfáà rẹ̀.+

  • Diutarónómì 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Wọn ò ní fún àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì àti gbogbo ẹ̀yà Léfì pátá ní ìpín tàbí ogún kankan ní Ísírẹ́lì. Wọ́n á máa jẹ lára àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, èyí tó jẹ́ tirẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́