Léfítíkù 11:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Torí èmi ni Jèhófà, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run,+ ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́,+ torí èmi jẹ́ mímọ́.+ 1 Kọ́ríńtì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 nígbà tí Ọlọ́run ń dá àwọn tó wà lóde lẹ́jọ́?+ “Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò láàárín yín.”+
45 Torí èmi ni Jèhófà, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run,+ ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́,+ torí èmi jẹ́ mímọ́.+