Nọ́ńbà 30:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Tí ọkùnrin kan bá jẹ́jẹ̀ẹ́+ fún Jèhófà tàbí tó búra+ pé òun máa* yẹra fún nǹkan kan, kò gbọ́dọ̀ yẹ ọ̀rọ̀ rẹ̀.+ Gbogbo ohun tó jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa ṣe ni kó ṣe.+ Sáàmù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kì í bá ẹnikẹ́ni tó jẹ́ oníwàkiwà kẹ́gbẹ́,+Àmọ́ ó máa ń bọlá fún àwọn tó bẹ̀rù Jèhófà. Kì í yẹ àdéhùn,* kódà tó bá máa pa á lára.+ Òwe 20:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ìdẹkùn ni téèyàn bá sọ láìronú pé, “Mímọ́!”+ Lẹ́yìn náà, kó ṣẹ̀ṣẹ̀ máa ronú lórí ẹ̀jẹ́ tó jẹ́.+
2 Tí ọkùnrin kan bá jẹ́jẹ̀ẹ́+ fún Jèhófà tàbí tó búra+ pé òun máa* yẹra fún nǹkan kan, kò gbọ́dọ̀ yẹ ọ̀rọ̀ rẹ̀.+ Gbogbo ohun tó jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun máa ṣe ni kó ṣe.+
4 Kì í bá ẹnikẹ́ni tó jẹ́ oníwàkiwà kẹ́gbẹ́,+Àmọ́ ó máa ń bọlá fún àwọn tó bẹ̀rù Jèhófà. Kì í yẹ àdéhùn,* kódà tó bá máa pa á lára.+