-
Jẹ́nẹ́sísì 19:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Àwọn ọmọbìnrin Lọ́ọ̀tì méjèèjì lóyún nípasẹ̀ bàbá wọn.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 19:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Èyí àbúrò náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bẹni-ámì. Òun ló wá di bàbá àwọn ọmọ Ámónì.+
-
-
Diutarónómì 2:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Jèhófà wá sọ fún mi pé, ‘Má ṣe bá Móábù fa wàhálà kankan, má sì bá wọn jagun, torí mi ò ní fún ọ ní ìkankan lára ilẹ̀ rẹ̀ pé kó di tìrẹ, torí mo ti fún àwọn àtọmọdọ́mọ Lọ́ọ̀tì ní Árì kó lè di tiwọn.+
-