ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 19:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “‘Tí ẹ bá ń kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pèéṣẹ́* irè oko yín.+

  • Léfítíkù 23:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “‘Tí ẹ bá kórè oko yín, ẹ ò gbọ́dọ̀ kárúgbìn eteetí oko yín tán, ẹ má sì ṣa ohun tó bá ṣẹ́ kù lẹ́yìn tí ẹ kórè.+ Kí ẹ fi í sílẹ̀ fún àwọn aláìní*+ àti àjèjì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”

  • Rúùtù 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Kí ẹ sì rí i pé ẹ yọ ṣírí ọkà díẹ̀ sílẹ̀ fún un lára èyí tí ẹ ti dì, kí ẹ sì fi wọ́n sílẹ̀ kó lè ṣà wọ́n, ẹ má ṣe bá a sọ ohunkóhun láti dá a dúró.”

  • Sáàmù 41:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń ro ti àwọn aláìní;+

      Jèhófà yóò gbà á sílẹ̀ ní ọjọ́ àjálù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́