-
Jeremáyà 15:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Màá jẹ́ kí wọ́n kó àwọn ohun àmúṣọrọ̀ rẹ àti ìṣúra rẹ lọ,+
Kì í ṣe láti gba owó, àmọ́ ó jẹ́ nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí o dá ní gbogbo ilẹ̀ rẹ.
-