Jẹ́nẹ́sísì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà. Jẹ́nẹ́sísì 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 àwọn ọba yìí bá Bérà ọba Sódómù+ jagun àti Bíṣà ọba Gòmórà,+ Ṣínábù ọba Ádímà, Ṣémébà ọba Sébóíímù+ àti ọba Bélà, ìyẹn Sóárì.
19 Ààlà àwọn ọmọ Kénáánì bẹ̀rẹ̀ láti Sídónì títí lọ dé Gérárì,+ nítòsí Gásà,+ títí lọ dé Sódómù, Gòmórà,+ Ádímà àti Sébóíímù,+ nítòsí Láṣà.
2 àwọn ọba yìí bá Bérà ọba Sódómù+ jagun àti Bíṣà ọba Gòmórà,+ Ṣínábù ọba Ádímà, Ṣémébà ọba Sébóíímù+ àti ọba Bélà, ìyẹn Sóárì.