-
Jóṣúà 6:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Wọ́n wá dáná sun ìlú náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀. Àmọ́ wọ́n kó fàdákà, wúrà àti àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà àti irin ṣe lọ síbi ìṣúra nínú ilé Jèhófà.+
-