Léfítíkù 27:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ ra ẹnikẹ́ni tí a máa pa run pa dà.+ Ṣe ni kí ẹ pa á.+ Diutarónómì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́, wàá sì ṣẹ́gun wọn.+ Kí o rí i pé o pa wọ́n run pátápátá.+ O ò gbọ́dọ̀ bá wọn dá májẹ̀mú kankan, o ò sì gbọ́dọ̀ ṣojúure sí wọn rárá.+
2 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́, wàá sì ṣẹ́gun wọn.+ Kí o rí i pé o pa wọ́n run pátápátá.+ O ò gbọ́dọ̀ bá wọn dá májẹ̀mú kankan, o ò sì gbọ́dọ̀ ṣojúure sí wọn rárá.+