ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 13:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 23:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù sin Sérà ìyàwó rẹ̀ sínú ihò tó wà ní Mákípẹ́là níwájú Mámúrè, ìyẹn ní Hébúrónì, ní ilẹ̀ Kénáánì.

  • Nọ́ńbà 13:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.

  • Jóṣúà 10:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Adoni-sédékì ọba Jerúsálẹ́mù wá ránṣẹ́ sí Hóhámù ọba Hébúrónì,+ Pírámù ọba Jámútì, Jáfíà ọba Lákíṣì àti Débírì ọba Ẹ́gílónì+ pé: 4 “Ẹ wá ràn mí lọ́wọ́, ká lè jọ gbógun ja Gíbíónì, torí ó ti bá Jóṣúà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe àdéhùn àlàáfíà.”+

  • Jóṣúà 15:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ó fún Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè, ní ìpín láàárín àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Jóṣúà, ìpín náà ni Kiriati-ábà, (Ábà ni bàbá Ánákì), ìyẹn Hébúrónì.+

  • Jóṣúà 21:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Wọ́n fún àwọn ọmọ àlùfáà Áárónì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Hébúrónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́