Jẹ́nẹ́sísì 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ Jẹ́nẹ́sísì 10:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 àwọn Hífì,+ àwọn Ákì, àwọn Sáínì, Jẹ́nẹ́sísì 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀. Ẹ́kísódù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Màá lọ gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì,+ màá sì mú wọn kúrò ní ilẹ̀ yẹn lọ sí ilẹ̀ kan tó dára, tó sì fẹ̀, ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn,+ ní agbègbè àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+
2 Nígbà tí Ṣékémù, ọmọ Hámórì, ọmọ Hífì,+ tó jẹ́ ìjòyè ilẹ̀ náà rí i, ó mú un, ó sì bá a sùn, ó fipá bá a lò pọ̀.
8 Màá lọ gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì,+ màá sì mú wọn kúrò ní ilẹ̀ yẹn lọ sí ilẹ̀ kan tó dára, tó sì fẹ̀, ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn,+ ní agbègbè àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+