Jóṣúà 21:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Wọ́n fún ìdílé àwọn ọmọ Mérárì,+ àwọn ọmọ Léfì tó ṣẹ́ kù ní àwọn ìlú yìí látinú ìpín ẹ̀yà Sébúlúnì:+ Jókínéámù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Kárítà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
34 Wọ́n fún ìdílé àwọn ọmọ Mérárì,+ àwọn ọmọ Léfì tó ṣẹ́ kù ní àwọn ìlú yìí látinú ìpín ẹ̀yà Sébúlúnì:+ Jókínéámù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Kárítà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,