Nọ́ńbà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì. Àwọn Onídàájọ́ 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Júdà tún lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Hébúrónì jà (Kiriati-ábà ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀), wọ́n sì pa Ṣéṣáì, Áhímánì àti Tálímáì.+ Àwọn Onídàájọ́ 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wọ́n fún Kélẹ́bù ní Hébúrónì, bí Mósè ṣe ṣèlérí,+ ó sì lé àwọn ọmọ Ánákì+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta kúrò níbẹ̀.
22 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Négébù, wọ́n dé Hébúrónì.+ Ibẹ̀ ni Áhímánì, Ṣéṣáì àti Tálímáì,+ tí wọ́n jẹ́ Ánákímù+ ń gbé. Ó ṣẹlẹ̀ pé, ọdún méje ni wọ́n ti kọ́ Hébúrónì ṣáájú Sóánì ti ilẹ̀ Íjíbítì.
10 Júdà tún lọ bá àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Hébúrónì jà (Kiriati-ábà ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀), wọ́n sì pa Ṣéṣáì, Áhímánì àti Tálímáì.+