Jóṣúà 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí náà, wọ́n ya Kédéṣì+ ní Gálílì sọ́tọ̀* ní agbègbè olókè Náfútálì, Ṣékémù+ ní agbègbè olókè Éfúrémù àti Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì, ní agbègbè olókè Júdà. 1 Àwọn Ọba 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Rèhóbóámù lọ sí Ṣékémù, nítorí gbogbo Ísírẹ́lì ti wá sí Ṣékémù+ láti fi í jọba.+
7 Torí náà, wọ́n ya Kédéṣì+ ní Gálílì sọ́tọ̀* ní agbègbè olókè Náfútálì, Ṣékémù+ ní agbègbè olókè Éfúrémù àti Kiriati-ábà,+ ìyẹn Hébúrónì, ní agbègbè olókè Júdà.