Jóṣúà 21:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Kò sí ìlérí* tí kò ṣẹ nínú gbogbo ìlérí dáadáa tí Jèhófà ṣe fún ilé Ísírẹ́lì; gbogbo rẹ̀ ló ṣẹ pátá.+ 1 Àwọn Ọba 8:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 “Ìyìn ni fún Jèhófà, tí ó fún àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì ní ibi ìsinmi bí ó ti ṣèlérí.+ Kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tí ó ṣe nípasẹ̀ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ó lọ láìṣẹ.+
45 Kò sí ìlérí* tí kò ṣẹ nínú gbogbo ìlérí dáadáa tí Jèhófà ṣe fún ilé Ísírẹ́lì; gbogbo rẹ̀ ló ṣẹ pátá.+
56 “Ìyìn ni fún Jèhófà, tí ó fún àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì ní ibi ìsinmi bí ó ti ṣèlérí.+ Kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tí ó ṣe nípasẹ̀ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ó lọ láìṣẹ.+