Ẹ́kísódù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+ Jóṣúà 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Wọ́n sọ fún Jóṣúà pé: “Jèhófà ti fi gbogbo ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́.+ Kódà, ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti domi nítorí wa.”+
15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+
24 Wọ́n sọ fún Jóṣúà pé: “Jèhófà ti fi gbogbo ilẹ̀ náà lé wa lọ́wọ́.+ Kódà, ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà ti domi nítorí wa.”+