1 Sámúẹ́lì 14:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 (Áhíjà ọmọ Áhítúbù,+ arákùnrin Íkábódì,+ ọmọ Fíníhásì,+ ọmọ Élì,+ àlùfáà Jèhófà ní Ṣílò+ tó ń wọ éfódì,+ sì wà pẹ̀lú wọn.) Àwọn èèyàn náà ò sì mọ̀ pé Jónátánì ti lọ.
3 (Áhíjà ọmọ Áhítúbù,+ arákùnrin Íkábódì,+ ọmọ Fíníhásì,+ ọmọ Élì,+ àlùfáà Jèhófà ní Ṣílò+ tó ń wọ éfódì,+ sì wà pẹ̀lú wọn.) Àwọn èèyàn náà ò sì mọ̀ pé Jónátánì ti lọ.