1 Sámúẹ́lì 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ṣùgbọ́n ó pe ọmọ náà ní Íkábódì,*+ ó ní: “Ògo ti kúrò ní Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn,”+ ó ń tọ́ka sí bí wọ́n ṣe gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ àti ohun tó ṣẹlẹ̀ sí bàbá ọkọ rẹ̀ àti ọkọ rẹ̀.+
21 Ṣùgbọ́n ó pe ọmọ náà ní Íkábódì,*+ ó ní: “Ògo ti kúrò ní Ísírẹ́lì lọ sí ìgbèkùn,”+ ó ń tọ́ka sí bí wọ́n ṣe gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ àti ohun tó ṣẹlẹ̀ sí bàbá ọkọ rẹ̀ àti ọkọ rẹ̀.+