Ẹ́kísódù 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí màá lọ káàkiri ilẹ̀ Íjíbítì lálẹ́ yìí, màá sì pa gbogbo àkọ́bí nílẹ̀ Íjíbítì, látorí èèyàn dórí ẹranko;+ màá sì dá gbogbo ọlọ́run Íjíbítì lẹ́jọ́.+ Èmi ni Jèhófà. 1 Kíróníkà 16:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Gbogbo ọlọ́run àwọn èèyàn jẹ́ ọlọ́run asán,+Àmọ́ Jèhófà ló dá ọ̀run.+ Sáàmù 97:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+
12 Torí màá lọ káàkiri ilẹ̀ Íjíbítì lálẹ́ yìí, màá sì pa gbogbo àkọ́bí nílẹ̀ Íjíbítì, látorí èèyàn dórí ẹranko;+ màá sì dá gbogbo ọlọ́run Íjíbítì lẹ́jọ́.+ Èmi ni Jèhófà.
7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+