Léfítíkù 11:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Torí èmi ni Jèhófà, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run,+ ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́,+ torí èmi jẹ́ mímọ́.+
45 Torí èmi ni Jèhófà, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run,+ ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́,+ torí èmi jẹ́ mímọ́.+