-
1 Sámúẹ́lì 8:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Síbẹ̀, àwọn èèyàn náà kò fetí sí ohun tí Sámúẹ́lì sọ fún wọn, wọ́n ní: “Àní sẹ́, a ti pinnu láti ní ọba tiwa.
-
-
1 Sámúẹ́lì 12:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ọba tí ẹ fẹ́ nìyí, ẹni tí ẹ béèrè. Ẹ wò ó! Jèhófà ti fi ọba jẹ lórí yín.+
-