Léfítíkù 27:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ ra ẹnikẹ́ni tí a máa pa run pa dà.+ Ṣe ni kí ẹ pa á.+ 1 Sámúẹ́lì 15:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹ̀yìn náà ni Jèhófà rán ọ níṣẹ́, ó sọ pé, ‘Lọ pa àwọn ọmọ Ámálékì tó jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ run pátápátá.+ Bá wọn jà títí wàá fi pa wọ́n run.’+
18 Ẹ̀yìn náà ni Jèhófà rán ọ níṣẹ́, ó sọ pé, ‘Lọ pa àwọn ọmọ Ámálékì tó jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ run pátápátá.+ Bá wọn jà títí wàá fi pa wọ́n run.’+