-
1 Sámúẹ́lì 21:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn ìránṣẹ́ Ákíṣì sọ fún un pé: “Ṣé kì í ṣe Dáfídì ọba ilẹ̀ náà nìyí? Ṣé òun kọ́ ni wọ́n kọrin fún, tí wọ́n ń jó tí wọ́n sì ń sọ pé,
‘Sọ́ọ̀lù ti pa ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀tá,
Àmọ́ Dáfídì pa ẹgbẹẹgbàárùn-ún ọ̀tá’?”+
-
-
1 Sámúẹ́lì 29:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣé kì í ṣe Dáfídì tí wọ́n kọrin fún, tí wọ́n sì ń jó fún nìyí, tí wọ́n ń sọ pé:
‘Sọ́ọ̀lù ti pa ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀tá,
Àmọ́ Dáfídì pa ẹgbẹẹgbàárùn-ún ọ̀tá’?”+
-