ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 18:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àwọn obìnrin tó ń ṣe ayẹyẹ náà ń kọrin pé:

      “Sọ́ọ̀lù ti pa ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀tá,

      Àmọ́ Dáfídì pa ẹgbẹẹgbàárùn-ún ọ̀tá.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 21:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àwọn ìránṣẹ́ Ákíṣì sọ fún un pé: “Ṣé kì í ṣe Dáfídì ọba ilẹ̀ náà nìyí? Ṣé òun kọ́ ni wọ́n kọrin fún, tí wọ́n ń jó tí wọ́n sì ń sọ pé,

      ‘Sọ́ọ̀lù ti pa ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀tá,

      Àmọ́ Dáfídì pa ẹgbẹẹgbàárùn-ún ọ̀tá’?”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́