1 Sámúẹ́lì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+ 1 Sámúẹ́lì 25:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jọ̀wọ́, dárí ìṣìnà ìránṣẹ́bìnrin rẹ jì í, nítorí ó dájú pé Jèhófà máa ṣe ilé tó máa wà títí láé fún olúwa mi,+ nítorí àwọn ogun Jèhófà ni olúwa mi ń jà+ àti pé kò sí ìwà ibi kankan tí a rí lọ́wọ́ rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+
13 Torí náà, Sọ́ọ̀lù mú un kúrò níwájú rẹ̀, ó sì yàn án ṣe olórí ẹgbẹ̀rún, Dáfídì sì máa ń kó àwọn ọmọ ogun náà lọ sójú ogun.*+
28 Jọ̀wọ́, dárí ìṣìnà ìránṣẹ́bìnrin rẹ jì í, nítorí ó dájú pé Jèhófà máa ṣe ilé tó máa wà títí láé fún olúwa mi,+ nítorí àwọn ogun Jèhófà ni olúwa mi ń jà+ àti pé kò sí ìwà ibi kankan tí a rí lọ́wọ́ rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.+