-
1 Sámúẹ́lì 16:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Bí Dáfídì ṣe wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù nìyẹn, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe ìránṣẹ́ rẹ̀.+ Sọ́ọ̀lù wá nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ gan-an, ó sì yàn án pé kó máa gbé ìhámọ́ra òun.
-
-
1 Sámúẹ́lì 18:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Láti ọjọ́ yẹn lọ, Sọ́ọ̀lù mú Dáfídì sọ́dọ̀, kò sì jẹ́ kó pa dà sí ilé bàbá rẹ̀.+
-