ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 15:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Torí pé ó ti tàbùkù sí ọ̀rọ̀ Jèhófà, kò sì pa àṣẹ rẹ̀ mọ́, ẹ gbọ́dọ̀ pa+ ẹni* náà. Ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ wà lọ́rùn rẹ̀.’”+

  • 1 Sámúẹ́lì 2:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nípa bẹ́ẹ̀, ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ náà wá pọ̀ gan-an níwájú Jèhófà,+ nítorí àwọn ọkùnrin náà hùwà àìlọ́wọ̀ sí ọrẹ Jèhófà.

  • 1 Sámúẹ́lì 3:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Sọ fún un pé màá ṣe ìdájọ́ tó máa wà títí láé fún ilé rẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó mọ̀ nípa rẹ̀,+ torí àwọn ọmọ rẹ̀ ń sọ̀rọ̀ òdì sí Ọlọ́run,+ àmọ́ kò bá wọn wí.+ 14 Ìdí nìyẹn tí mo fi búra fún ilé Élì pé ẹbọ tàbí ọrẹ kò ní lè pẹ̀tù sí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Élì láé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́