-
Léfítíkù 8:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Níkẹyìn, ó dà lára òróró àfiyanni sórí Áárónì, ó sì fòróró yàn án láti sọ ọ́ di mímọ́.+
-
-
Nọ́ńbà 17:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbà tí Mósè wọnú àgọ́ Ẹ̀rí lọ́jọ́ kejì, wò ó! ọ̀pá Áárónì tó fi ṣojú fún ilé Léfì ti rúwé,* ó hù, ó yọ òdòdó, àwọn èso álímọ́ńdì tó ti pọ́n sì yọ lórí rẹ̀.
-