16 Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀.+ Kí wọ́n fi ṣe búrẹ́dì aláìwú, kí wọ́n jẹ ẹ́ ní ibi mímọ́. Kí wọ́n jẹ ẹ́ ní àgbàlá àgọ́ ìpàdé.+
14 Kí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ tún jẹ igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́+ ní ibi tó mọ́, torí mo ti fi ṣe ìpín rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ látinú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
9 Èyí ló máa jẹ́ tìrẹ nínú ọrẹ mímọ́ jù lọ tí wọ́n fi iná sun: gbogbo ọrẹ tí wọ́n bá mú wá, títí kan àwọn ọrẹ ọkà+ wọn àtàwọn ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ wọn pẹ̀lú àwọn ẹbọ ẹ̀bi+ wọn tí wọ́n mú wá fún mi. Ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́ fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ.