14 Dáfídì ń gbé ní aginjù ní àwọn ibi tó ṣòroó dé, ní agbègbè olókè tó wà ní aginjù Sífù.+ Gbogbo ìgbà ni Sọ́ọ̀lù ń wá a kiri,+ àmọ́ Jèhófà kò fi lé e lọ́wọ́.
19 Lẹ́yìn náà, àwọn ọkùnrin Sífù lọ sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù ní Gíbíà,+ wọ́n sọ pé: “Ṣebí tòsí wa ni Dáfídì fara pa mọ́ sí,+ ní àwọn ibi tó ṣòroó dé ní Hóréṣì,+ lórí òkè Hákílà,+ tó wà ní gúúsù* Jéṣímónì.*+
Sí olùdarí; kí a kọ ọ́ pẹ̀lú àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín. Másíkílì.* Ti Dáfídì, nígbà tí àwọn ọmọ Sífù wá sọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù, tí wọ́n sì sọ fún un pé: “Àárín wa ni Dáfídì fara pa mọ́ sí.”+