ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 8:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà ni olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì sì di olórí àwọn òjíṣẹ́.*

  • 1 Àwọn Ọba 1:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Lẹ́yìn náà, àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì àti Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà pẹ̀lú àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì+ jáde lọ, wọ́n ní kí Sólómọ́nì gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* Ọba Dáfídì,+ wọ́n sì mú un wá sí Gíhónì.+

  • 1 Kíróníkà 18:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ni olórí àwọn Kérétì+ àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì ló sì wà ní ipò iwájú lẹ́yìn ọba.

  • Ìsíkíẹ́lì 25:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Màá na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ àwọn Filísínì,+ màá pa àwọn Kérétì rẹ́,+ màá sì run àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn tó ń gbé ní etí òkun.+

  • Sefanáyà 2:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 “Ẹ gbé! Ẹ̀yin tó ń gbé etí òkun, orílẹ̀-èdè àwọn Kérétì.+

      Jèhófà ti bá yín wí.

      Ìwọ Kénáánì, ilẹ̀ àwọn Filísínì, màá pa ọ́ run,

      Tí kò fi ní sí olùgbé kan tó máa ṣẹ́ kù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́