-
1 Kíróníkà 10:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Bí Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ṣe kú nìyẹn, tí gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀ sì kú pa pọ̀.+ 7 Nígbà tí gbogbo àwọn èèyàn Ísírẹ́lì tó wà ní àfonífojì* rí i pé gbogbo èèyàn ti sá lọ àti pé Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀ ti kú, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fi àwọn ìlú wọn sílẹ̀, wọ́n sì sá lọ; lẹ́yìn náà, àwọn Filísínì wá, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀.
-