1 Sámúẹ́lì 31:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn Filísínì sún mọ́ Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn Filísínì sì pa Jónátánì,+ Ábínádábù àti Maliki-ṣúà, àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù.+ 2 Sámúẹ́lì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ Ábínérì+ ọmọ Nérì, olórí ọmọ ogun Sọ́ọ̀lù ti mú Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù sọdá sí Máhánáímù,+
2 Àwọn Filísínì sún mọ́ Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn Filísínì sì pa Jónátánì,+ Ábínádábù àti Maliki-ṣúà, àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù.+