ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 O máa ki àwọn ọ̀pá náà bọ inú àwọn òrùka tó wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì Àpótí náà, kí ẹ lè máa fi gbé Àpótí náà.

  • Nọ́ńbà 7:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ kò fún àwọn ọmọ Kóhátì ní ìkankan, torí ojúṣe wọn jẹ mọ́ iṣẹ́ ibi mímọ́,+ èjìká+ ni wọ́n sì máa ń fi ru àwọn ohun mímọ́.

  • Jóṣúà 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tí àwọn èèyàn náà kúrò nínú àgọ́ wọn, kété kí wọ́n tó sọdá Jọ́dánì, àwọn àlùfáà tó gbé àpótí+ májẹ̀mú ń lọ níwájú àwọn èèyàn náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́