ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 14:49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+

  • 1 Sámúẹ́lì 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Míkálì, ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù,+ nífẹ̀ẹ́ Dáfídì gan-an, wọ́n sọ fún Sọ́ọ̀lù nípa rẹ̀, inú rẹ̀ sì dùn sí i.

  • 1 Sámúẹ́lì 18:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ lọ, wọ́n sì pa igba (200) lára àwọn ọkùnrin Filísínì, Dáfídì kó gbogbo adọ̀dọ́ wọn wá fún ọba, kó lè bá ọba dána. Torí náà, Sọ́ọ̀lù fún un ní Míkálì ọmọ rẹ̀ láti fi ṣe aya.+

  • 2 Sámúẹ́lì 3:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Lẹ́yìn náà, Dáfídì rán àwọn òjíṣẹ́ sí Íṣí-bóṣétì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù, pé: “Fún mi ní Míkálì ìyàwó mi, ẹni tí mo fi ọgọ́rùn-ún (100) adọ̀dọ́ àwọn Filísínì+ fẹ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́