ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 18:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá arábìnrin rẹ lò pọ̀, ì báà jẹ́ ọmọ bàbá rẹ tàbí ọmọ ìyá rẹ, ì báà jẹ́ agbo ilé kan náà ni wọ́n bí yín sí tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́.+

  • Léfítíkù 18:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe èyíkéyìí nínú àwọn ohun ìríra yìí, kí ẹ pa gbogbo àwọn* tó bá ń ṣe é, kí ẹ lè mú wọn kúrò láàárín àwọn èèyàn wọn.

  • Léfítíkù 20:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá arábìnrin rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ tàbí ọmọ ìyá rẹ̀ lò pọ̀, tó rí ìhòòhò obìnrin náà, tí obìnrin náà sì rí ìhòòhò rẹ̀, ohun ìtìjú ni.+ Kí ẹ pa wọ́n níṣojú àwọn ọmọ àwọn èèyàn wọn. Ó ti dójú ti* arábìnrin rẹ̀. Kó jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.

  • Diutarónómì 27:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá bá arábìnrin rẹ̀ sùn, ì báà jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ tàbí ọmọ ìyá rẹ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́