2 Sámúẹ́lì 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nígbà tí Dáfídì dé orí òkè tí àwọn èèyàn ti máa ń forí balẹ̀ fún Ọlọ́run, Húṣáì+ ará Áríkì+ wá pàdé rẹ̀ níbẹ̀, ẹ̀wù rẹ̀ ti ya, iyẹ̀pẹ̀ sì wà lórí rẹ̀. 2 Sámúẹ́lì 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà tí Húṣáì+ ará Áríkì,+ ọ̀rẹ́* Dáfídì, wọlé wá sọ́dọ̀ Ábúsálómù, Húṣáì sọ fún Ábúsálómù pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!+ Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”
32 Nígbà tí Dáfídì dé orí òkè tí àwọn èèyàn ti máa ń forí balẹ̀ fún Ọlọ́run, Húṣáì+ ará Áríkì+ wá pàdé rẹ̀ níbẹ̀, ẹ̀wù rẹ̀ ti ya, iyẹ̀pẹ̀ sì wà lórí rẹ̀.
16 Nígbà tí Húṣáì+ ará Áríkì,+ ọ̀rẹ́* Dáfídì, wọlé wá sọ́dọ̀ Ábúsálómù, Húṣáì sọ fún Ábúsálómù pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!+ Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”