18 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ kúrò* àti gbogbo àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì+ àti àwọn ará Gátì,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) ọkùnrin tí wọ́n tẹ̀ lé e láti Gátì,+ sì ń kọjá bí ọba ti ń yẹ̀ wọ́n wò.*
38 Lẹ́yìn náà, àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì àti Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà pẹ̀lú àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì+ jáde lọ, wọ́n ní kí Sólómọ́nì gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* Ọba Dáfídì,+ wọ́n sì mú un wá sí Gíhónì.+