1 Sámúẹ́lì 18:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jónátánì àti Dáfídì dá májẹ̀mú,+ torí pé ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara rẹ̀.*+ 1 Sámúẹ́lì 20:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Jónátánì sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ ní àlàáfíà, nítorí àwa méjèèjì ti fi orúkọ Jèhófà búra+ pé, ‘Kí Jèhófà wà láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn ọmọ* mi àti àwọn ọmọ* rẹ títí láé.’”+ Dáfídì bá dìde, ó sì lọ, Jónátánì wá pa dà sínú ìlú.
42 Jónátánì sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ ní àlàáfíà, nítorí àwa méjèèjì ti fi orúkọ Jèhófà búra+ pé, ‘Kí Jèhófà wà láàárín èmi àti ìwọ àti láàárín àwọn ọmọ* mi àti àwọn ọmọ* rẹ títí láé.’”+ Dáfídì bá dìde, ó sì lọ, Jónátánì wá pa dà sínú ìlú.